Nigerian fast-rising gospel music minister, Olabisi Deborah debuts with a fantastic song of the moment titled ‘Imole De’.
The emerging act puts forth all accolades to give you a fantasy worship song on this wonderful delivery. Imole De echoes an excerpt of adoration to God almighty which the music act blends with her fascinating voice and a darling production from the guru himself, Kell Console. Download and enjoy this soul-lifting tune.
DOWNLOAD MP3: Olabisi Deborah – Imole De
Lyrics: Imole De by Olabisi Deborah
Call:- Nigbati idanwo ba de
Resp:- Oluwa so mi o kin ma su bu
Call:- Nigbati iji aye ba nfe
Resp:- Jowo so mi o ko ma se gbe mi lo
Call:- Nigbati wahala aye de
Resp:- Oluwa so mi k’emi ma su bu.
Call:- Nigbati omi aye ba nru
Resp:- Jowo so mi o, ko ma se gbe mi lo.
All:- Oluwa la la bo mi
Iwo ni alabo mi
Olugbala mi o, ma so mi.
1. Ma a so mi, alabo mi,
Ma a to igbese mi gbogbo ninu aye ,
Jowo komi yo ninu ewu gbogbo,
Kin ma shirin, kin ma sii se
Kin ma daamu, kin ma mo si Olorun mi.
Igbekele mi wa ninu re o baba,
Amona to to julo o ma sho mi.
(B.t.c)
2.Nigba okunkun su’bole
Ti ko s’ibi ta le sa si
Nigbati arun kun aye
Ti ireti gbogbo pin
All: A gb’oju s’oke si o imole aye
Tan imole re/2*
S’aye wa o imole aye.
Call:- A gb’oju wa s’oke si o
All: A gb’oju s’oke si o imole aye
Tan imole re/2*
S’aye wa o imole.
Call:- Jesu, iwo ti se imole aye dakun tan imole re
All:- Repeat
Call:- Okunkun to su l’ori l’ede yi o, bawa tan mo le re si.
All:- Repeat
Call:- Baba imole, Okunkun ole si ni bi to ba wa, baba ba wa daa si
All:- Repeat
Call: A gb’oju wa s’oke ni bi ti iranlowo wa gbe wa
All:- Repeat.
Bridge:- Imole ti de o/2*
Okunkun parada
Imole ti de.
Oti tan mole s’ona mi, ona mi mole kedere/2*
M’oje ninu imole,
M’omu ninu imole,
Ohun gbogbo ninu imole
Tori imole ti de
Okunkun parada
Imole ti de.
Credit:
Songwriter: Olabisi Deborah
Producer’s By Kell Console.
For Booking; contact :+234703 840 4797


One thought on “[NEW MUSIC] Olabisi Deborah – Imole De (With Lyrics)”